Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 2

ATUDE FUN TI WONBA BAFI AISAN DENI MONLE

Eeru ela, 16", eepo obo die, ao wa gun tiyo kunna, aopo mo

ose dudu, aoko ose yi sinu igba olomori, tabi ike funfun

olomori, ao wa te ori ose yini ifa, irosun oso, aope

Gboloun resi, ao mafi omi gbigbona we pelu kankan tuntun nigbati

abati setan atisun lale ti akosi gbodo ba eni kankan soro mon ti

ile yofi mon ofore--= ariori, amonori, oge mowo, oge mese,

ajoji o wolu kiwon ofi igango sawo, idanre danre, awo aboju

danre danre, awo aboju danre danre, awon mejeje {7) oba

niwon fi won je larin awon aje, wonni eniti awon koba mu,

enikan kolemu eniti awon koba baja, enikankan kole baja, eniti

awon koba pa, eni kankan koleripa, eyin leni ti oba sebi ti emi-

----omo----- kape irosun oso, ifa to jagun tosi segun, ki oso,


aje, emere, {e,t,c} omale mumide, kiwon o male bami jao,

kiwon o male pami o, irosun osooo, bami segun gbogbo awon

ota mi,

You might also like