Wikipedia:Ṣé ẹ mọ̀ pé...
Appearance
Ṣé ẹ mọ̀ pé...
- ... pé oṣù kẹjọ August gba orúkọ rẹ̀ látọwọ́ orúkọ Augustus Caesar?
- ... pé ohun kan lórí plánẹ̀tì Júpítérì yíò wúwo ju orí plánẹ̀tì Ayé lọ ní ìlọ́po lọ́nà 2.53. Fún àpẹrẹ tí ènìyàn kan bá wúwo tó kílò 70 lórí ilẹ̀ Ayé, onítòhún yíò wúwo tóbi ju kílò 177 lọ lórí Júpítéri. Júpítérì kò ní ilẹ̀ẹ́lẹ̀, ẹ̀fúùfù ni gbogbo ara rẹ̀.
![]() | Ẹ le dá àbá nípa Ṣé ẹ mọ̀ pé... ojowaju níbí Àwọn tó hàn tẹ́lẹ̀ wà níbí |
![]() | ojúewé yìí ti jẹ dídá àbò bò láti ṣàtúnṣe sí. See the protection policy and protection log for more details. Please discuss any changes on the talk page; you may submit an edit request to ask an administrator to make an edit if it is uncontroversial or supported by consensus. You may also request that this page be unprotected. |